Timoti Keji 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn tí wọ́n ti ṣìnà kúrò ninu òtítọ́, tí wọn ń sọ pé ajinde tiwa ti ṣẹlẹ̀, tí wọn ń mú kí igbagbọ ẹlòmíràn yẹ̀.

Timoti Keji 2

Timoti Keji 2:13-19