Timoti Keji 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Sí Timoti, àyànfẹ́ ọmọ mi.Kí oore-ọ̀fẹ́, àánú ati alaafia láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun Baba, ati Kristi Jesu, Oluwa wa, wà pẹlu rẹ.

Timoti Keji 1

Timoti Keji 1:1-10