Timoti Keji 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Oluwa ṣàánú ìdílé Onesiforosi. Kò ní iye ìgbà tí ó ti tù mí ninu, ninu ìṣòro mi. Kò tijú pé ẹlẹ́wọ̀n ni mí.

Timoti Keji 1

Timoti Keji 1:15-18