Timoti Keji 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ètò yìí ni ó wá hàn kedere nisinsinyii nípa ìfarahàn olùgbàlà wa Kristi Jesu, tí ó gba agbára lọ́wọ́ ikú, tí ó mú ìyè ati àìkú wá sinu ìmọ́lẹ̀ nípa ìyìn rere.

Timoti Keji 1

Timoti Keji 1:5-18