Tẹsalonika Kinni 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan bá ń wí pé, “Àkókò alaafia ati ìrọ̀ra nìyí,” nígbà náà ni ìparun yóo dé bá wọn lójijì, wọn kò sì ní ríbi sá sí; yóo dàbí ìgbà tí obinrin bá lóyún, tí kò mọ ìgbà tí òun yóo bí.

Tẹsalonika Kinni 5

Tẹsalonika Kinni 5:1-13