Tẹsalonika Kinni 5:27-28 BIBELI MIMỌ (BM)

27. Mo fi Oluwa bẹ̀ yín, ẹ ka ìwé yìí fún gbogbo ìjọ.

28. Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa wa Jesu Kristi kí ó wà pẹlu yín.

Tẹsalonika Kinni 5