Tẹsalonika Kinni 5:26-28 BIBELI MIMỌ (BM)

26. Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí gbogbo àwọn onigbagbọ.

27. Mo fi Oluwa bẹ̀ yín, ẹ ka ìwé yìí fún gbogbo ìjọ.

28. Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa wa Jesu Kristi kí ó wà pẹlu yín.

Tẹsalonika Kinni 5