Tẹsalonika Kinni 5:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Ọlọrun alaafia kí ó yà yín sí mímọ́ patapata; kí ó pa gbogbo ẹ̀mí yín mọ́ ati ọkàn, ati ara yín. Kí èyíkéyìí má ní àbùkù nígbà tí Oluwa wa Jesu Kristi bá farahàn.

Tẹsalonika Kinni 5

Tẹsalonika Kinni 5:14-25