Tẹsalonika Kinni 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbìyànjú láti fi ọkàn yín balẹ̀. Ẹ má máa yọjú sí nǹkan oní-ǹkan. Ẹ tẹpá mọ́ṣẹ́, gẹ́gẹ́ bí a ti sọ fun yín.

Tẹsalonika Kinni 4

Tẹsalonika Kinni 4:6-18