Tẹsalonika Kinni 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé bí ẹ bá dúró gbọningbọnin ninu Oluwa nisinsinyii, a jẹ́ pé wíwà láàyè wa kò jẹ́ lásán.

Tẹsalonika Kinni 3

Tẹsalonika Kinni 3:1-9