Tẹsalonika Kinni 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ọ̀rọ̀ ìyànjú wa kì í ṣe ohun ìṣìnà, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe ohun èérí tabi ti ìtànjẹ.

Tẹsalonika Kinni 2

Tẹsalonika Kinni 2:1-8