Tẹsalonika Kinni 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Juu yìí ni wọ́n pa Oluwa Jesu ati àwọn wolii, tí wọ́n sì fi inúnibíni lé wa jáde. Wọn kò ṣe ohun tí ó wu Ọlọrun, wọ́n sì ń lòdì sí àwọn ohun tí ó lè ṣe eniyan ní anfaani.

Tẹsalonika Kinni 2

Tẹsalonika Kinni 2:13-19