Tẹsalonika Kinni 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin náà wá ń fara wé wa, ẹ sì ń fara wé Oluwa. Láàrin ọpọlọpọ inúnibíni ẹ gba ọ̀rọ̀ ìyìn rere tayọ̀tayọ̀ láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí Mímọ́.

Tẹsalonika Kinni 1

Tẹsalonika Kinni 1:1-10