Tẹsalonika Keji 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

A ní ìdánilójú ninu Oluwa nípa yín pé àwọn ohun tí a ti sọ, tí ẹ sì ń ṣe, ni ẹ óo máa ṣe.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:1-5