Tẹsalonika Keji 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ tún máa gbadura pé kí Ọlọrun gbà wá lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú ati àwọn ìkà, nítorí kì í ṣe gbogbo eniyan ni ó gbàgbọ́.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:1-12