Tẹsalonika Keji 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Oluwa alaafia fúnrarẹ̀ fun yín ní alaafia nígbà gbogbo lọ́nà gbogbo. Kí Oluwa wà pẹlu gbogbo yín.

Tẹsalonika Keji 3

Tẹsalonika Keji 3:7-18