Tẹsalonika Keji 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

kí gbogbo àwọn tí kò gba òtítọ́ gbọ́ lè gba ìdálẹ́bi, àní, àwọn tí wọ́n ní inú dídùn sí ìwà ibi.

Tẹsalonika Keji 2

Tẹsalonika Keji 2:10-13