Tẹsalonika Keji 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn yìí ni wọn yóo gba ìdálẹ́bi sí ìparun ayérayé, wọn yóo sì kúrò níwájú Oluwa ati ògo agbára rẹ̀;

Tẹsalonika Keji 1

Tẹsalonika Keji 1:1-12