Tẹsalonika Keji 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

ati láti fún ẹ̀yin tí wọn ń pọ́n lójú, ati àwa náà ní ìsinmi, nígbà tí Oluwa wa, Jesu, bá farahàn láti ọ̀run ninu ọwọ́ iná pẹlu àwọn angẹli tí wọ́n jẹ́ alágbára.

Tẹsalonika Keji 1

Tẹsalonika Keji 1:1-12