Tẹsalonika Keji 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwa fúnra wa ń fọ́nnu nípa yín láàrin àwọn ìjọ Ọlọrun. À ń ròyìn ìfaradà ati igbagbọ yín ninu gbogbo inúnibíni ati ìpọ́njú tí ẹ̀ ń faradà.

Tẹsalonika Keji 1

Tẹsalonika Keji 1:1-7