Sefanaya 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ní, ‘Dájúdájú, wọn óo bẹ̀rù mi, wọn óo gba ìbáwí, wọn óo sì fọkàn sí gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún wọn.’ Ṣugbọn, ń ṣe ni wọ́n ń múra kankan,

Sefanaya 3

Sefanaya 3:1-17