Sefanaya 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ etí òkun yóo di pápá oko fún àwọn darandaran, ati ibi tí àwọn ẹran ọ̀sìn yóo ti máa jẹko.

Sefanaya 2

Sefanaya 2:1-9