Sefanaya 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo sá kúrò ní ìlú Gasa; ìlú Aṣikeloni yóo dahoro; a óo lé àwọn ará ìlú Aṣidodu jáde lọ́sàn-án gangan, a óo sì tú ìlú Ekironi ká.

Sefanaya 2

Sefanaya 2:2-7