Sefanaya 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA óo dẹ́rùbà wọ́n, yóo sọ gbogbo oriṣa ilé ayé di òfo, olukuluku eniyan yóo sì máa sin OLUWA ní ààyè rẹ̀ ní gbogbo orílẹ̀-èdè.

Sefanaya 2

Sefanaya 2:8-13