Sefanaya 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, n óo jẹ àwọn tí ń fo ẹnu ọ̀nà kọjá bí àwọn abọ̀rìṣà níyà, ati àwọn tí ń fi ìwà ipá, ati olè jíjà kó nǹkan kún ilé oriṣa wọn.”

Sefanaya 1

Sefanaya 1:4-15