Samuẹli Kinni 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá dá a lóhùn pé, “O ṣeun, jẹ́ kí á lọ.” Wọ́n bá lọ sí ìlú tí eniyan Ọlọrun yìí wà.

Samuẹli Kinni 9

Samuẹli Kinni 9:1-15