Samuẹli Kinni 8:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn eniyan náà kọ̀, wọn kò gba ohun tí Samuẹli wí gbọ́. Wọ́n ní, “Rárá o! A ṣá fẹ́ ní ọba ni.

Samuẹli Kinni 8

Samuẹli Kinni 8:9-22