Samuẹli Kinni 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, yóo pada lọ sí ilé rẹ̀, ní Rama, nítorí pé a máa dájọ́ fún àwọn eniyan níbẹ̀ pẹlu. Ó sì tẹ́ pẹpẹ kan sibẹ fún OLUWA.

Samuẹli Kinni 7

Samuẹli Kinni 7:13-17