Samuẹli Kinni 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn eniyan Israẹli ṣe ṣẹgun àwọn ará Filistia, wọn kò sì gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli mọ́. OLUWA n ṣe àwọn ará Filistia níbi ní gbogbo ọjọ́ ayé Samuẹli.

Samuẹli Kinni 7

Samuẹli Kinni 7:3-17