Samuẹli Kinni 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọba Filistini ń wò wọ́n bí wọ́n ti ń ṣe, lẹ́yìn náà, wọ́n yipada sí ìlú Ekironi ní ọjọ́ náà gan-an.

Samuẹli Kinni 6

Samuẹli Kinni 6:14-21