Samuẹli Kinni 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé àpótí OLUWA sinu kẹ̀kẹ́ ẹrù náà, pẹlu àpótí tí wọ́n kó àwọn èkúté wúrà ati kókó ọlọ́yún wúrà náà sí.

Samuẹli Kinni 6

Samuẹli Kinni 6:3-21