Samuẹli Kinni 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí àpótí Ọlọrun náà dé Gati, OLUWA jẹ ìlú náà níyà, ó mú kí gbogbo ara wọn kún fún kókó ọlọ́yún ati àgbà ati èwe wọn, ó sì mú ìpayà bá gbogbo wọn.

Samuẹli Kinni 5

Samuẹli Kinni 5:4-12