Samuẹli Kinni 5:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA jẹ àwọn ará ìlú Aṣidodu níyà gidigidi, ó sì dẹ́rùbà wọ́n. Ìyà tí ó fi jẹ wọ́n, ati àwọn tí wọn ń gbé agbègbè wọn ni pé gbogbo ara wọn kún fún kókó ọlọ́yún.

Samuẹli Kinni 5

Samuẹli Kinni 5:4-12