Samuẹli Kinni 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ara gbogbo àwọn tí kò kú ninu wọn kún fún kókó ọlọ́yún. Ariwo àwọn eniyan náà sì pọ̀ pupọ.

Samuẹli Kinni 5

Samuẹli Kinni 5:9-12