Samuẹli Kinni 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Eli gbọ́ igbe wọn, ó bèèrè pé, “Kí ni wọ́n ń kígbe báyìí fún?” Ọkunrin náà bá yára wá sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún Eli.

Samuẹli Kinni 4

Samuẹli Kinni 4:5-16