Samuẹli Kinni 31:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gé orí Saulu, wọ́n sì bọ́ ihamọra rẹ̀, wọ́n ranṣẹ lọ sí gbogbo ilẹ̀ Filistini, pé kí wọ́n kéde ìròyìn ayọ̀ náà fún gbogbo eniyan ati ní gbogbo ilé oriṣa wọn.

Samuẹli Kinni 31

Samuẹli Kinni 31:8-13