Samuẹli Kinni 31:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọmọkunrin náà rí i pé Saulu kú, òun náà fa idà rẹ̀ yọ, ó ṣubú lé e lórí ó sì kú.

Samuẹli Kinni 31

Samuẹli Kinni 31:1-13