Samuẹli Kinni 31:12 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn tí wọ́n jẹ́ akọni ninu wọ́n lọ sí Beti Ṣani lóru, wọ́n sì gbé òkú Saulu ati ti àwọn ọmọ rẹ̀ kúrò lára odi Beti Ṣani, wá sí Jabeṣi Gileadi, wọ́n sì sin wọ́n sibẹ.

Samuẹli Kinni 31

Samuẹli Kinni 31:11-13