Samuẹli Kinni 30:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá bèèrè lọ́wọ́ OLUWA pé, “Ṣé kí n lépa àwọn ọmọ ogun náà? Ṣé n óo bá wọn?”OLUWA sì dáhùn pé, “Lépa wọn, o óo bá wọn, o óo sì gba àwọn eniyan rẹ.”

Samuẹli Kinni 30

Samuẹli Kinni 30:2-16