Samuẹli Kinni 30:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gba gbogbo àwọn ẹran ọ̀sìn pẹlu. Àwọn eniyan náà sì ń dá àwọn ẹran ọ̀sìn náà jọ níwájú Dafidi, wọ́n ń sọ pé, “Ìkógun Dafidi nìyí.”

Samuẹli Kinni 30

Samuẹli Kinni 30:10-30