Samuẹli Kinni 30:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ keji, Dafidi kọlù wọ́n, ó sì pa wọ́n títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà. Kò sì sí ẹni tí ó là ninu wọn, àfi irinwo ọdọmọkunrin tí wọ́n gun ràkúnmí sá lọ.

Samuẹli Kinni 30

Samuẹli Kinni 30:7-24