Samuẹli Kinni 30:14 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti jagun ní Nẹgẹbu ní agbègbè Kereti ati ní agbègbè Juda ati ní agbègbè Nẹgẹbu ti Kalebu, a sì sun Sikilagi níná.”

Samuẹli Kinni 30

Samuẹli Kinni 30:13-19