OLUWA pe Samuẹli nígbà kẹta, ó bá tún dìde, ó tọ Eli lọ, ó ní “Ìwọ ni o pè mí; mo dé.”Eli wá mọ̀ nígbà náà pé, OLUWA ni ó ń pe ọmọ náà.