Samuẹli Kinni 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tún pe Samuẹli. Samuẹli dìde, ó tún tọ Eli lọ, ó ní, “Ìwọ ni o pè mí; mo dé.” Eli tún dá a lóhùn pé, “N kò pè ọ́, ọmọ mi, pada lọ sùn.”

Samuẹli Kinni 3

Samuẹli Kinni 3:1-7