Samuẹli Kinni 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti sọ fún un pé n óo jẹ ìdílé rẹ̀ níyà títí lae, nítorí pé àwọn ọmọ rẹ̀ ti ṣe nǹkan burúkú sí mi. Eli mọ̀ pé wọ́n ń ṣe bẹ́ẹ̀ ṣugbọn kò dá wọn lẹ́kun.

Samuẹli Kinni 3

Samuẹli Kinni 3:9-21