Samuẹli Kinni 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá sọ fún un pé, “Mo múra tán láti ṣe nǹkankan ní Israẹli, ohun tí mo fẹ́ ṣe náà yóo burú tóbẹ́ẹ̀ tí yóo ya ẹnikẹ́ni tí ó bá gbọ́ lẹ́nu.

Samuẹli Kinni 3

Samuẹli Kinni 3:10-19