Samuẹli Kinni 29:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Akiṣi sì dáhùn pé, “Nítòótọ́ ni, mo mọ̀ pé o jẹ́ ẹni rere bí angẹli OLUWA, ṣugbọn àwọn olórí ogun ti sọ pé, o kò lè bá wa lọ sójú ogun.

Samuẹli Kinni 29

Samuẹli Kinni 29:2-10