Samuẹli Kinni 28:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bèèrè pé, “Báwo ló rí?”Obinrin náà dáhùn pé, “Ọkunrin arúgbó kan ló ń bọ̀, ó sì fi aṣọ bora.”Saulu mọ̀ pé Samuẹli ni, ó sì tẹríba.

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:13-17