Samuẹli Kinni 28:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ṣe, àwọn ará Filistia kó ara wọn jọ láti bá Israẹli jagun. Akiṣi sọ fún Dafidi pé, “Ìwọ ati àwọn ọkunrin tí wọ́n wà pẹlu rẹ yóo jà fún mi.”

Samuẹli Kinni 28

Samuẹli Kinni 28:1-2