Samuẹli Kinni 26:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Abiṣai bá sọ fún Dafidi pé, “Ọlọrun ti fi ọ̀tá rẹ lé ọ lọ́wọ́ ní òní yìí, gbà mí láàyè kí n yọ ọ̀kọ̀, kí n sì gún un ní àgúnpa lẹ́ẹ̀kanṣoṣo.”

Samuẹli Kinni 26

Samuẹli Kinni 26:4-10